Revelation of John 16:1

Àwọn ago ìbínú Ọlọ́run

1 aMo sì gbọ́ ohùn ńlá kan láti inú tẹmpili wá, ń wí fún àwọn angẹli, méje nì pé, “Ẹ lọ, ẹ sì tú ago ìbínú Ọlọ́run wọ̀n-ọn-nì sí orí ayé.”

Copyright information for YorBMYO